Home Entertainment Bàba-bàbá mi kọ́ ilé méjìdínlọ́gọ́ta sí Èkó, àmọ́ kó wíìlì fún wa – Funmi Bank- Anthony.

Bàba-bàbá mi kọ́ ilé méjìdínlọ́gọ́ta sí Èkó, àmọ́ kó wíìlì fún wa – Funmi Bank- Anthony.

Onsere onitiata Yoruba, Funmi Bank-Anthony ti salaye ninu iforowanilenwo nipa idile ti o tinwa ati awon igbese ti o sun lati gbe.

O si salaye pe oun o lo oruko baba baba oun lati de ipo ti oun wa lonii ninu ise tiata. O si eyi ninu ifoworowanilenuwo pelu The Sun,

O ni’ “loooto ni oruko baba baba mi je gbajumo, amo mi o lo lati de ipo ti mo ma lenu ise mi lonii. Mi o le fi oruko naa gba owo ni ile ifowopamo. O ti se titie nigba to wa laye. O ti ko oruko tie, emi naa si n gbiyanju lati ko temi. Mi o ti de idaji ibi ti o wun mi lati de, bi o tile je pe o je oruko ti awon eeyan le ro mọ.”

Funmi Bank-Anthony ti fi han pe baba baba oun ko ile mejidinlogota si eko amo o wiili gbogbo re fun awon omo alainiya, o si salaye pe oun yoo ma saanu fun awon eeyan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…