Home orisiirisii Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n bá agbárí èèyàn lọ́wọ́ wọn.

Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n bá agbárí èèyàn lọ́wọ́ wọn.

Awon olopaa ipinle Oyo ti mu awon okunrin meji ti won n je Basiru Abdullahi ati Martin Adekola, ti wọn je omo ile Oja Funi ni Dde ni ipinle Osun, leyin ti won ba agari awon eeyan lowo won.

Komisona olopaa fun ipinle naa,Ogbeni Shina Olukoku so fun awon oniroyin pe won ko won po mo awon metalelaadota miiran fun esun ole jija ati egbe okunkun ni July 11, leyin ti won ko le salaye to peye bi agbari awon eeyan se de owo won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…