Home orisiirisii Àwọn ẹni ibi ti fi ipa ba ọmọdé obìnrin lòpọ̀ ni Ibadan.
orisiirisii - Orisirisi - July 13, 2019

Àwọn ẹni ibi ti fi ipa ba ọmọdé obìnrin lòpọ̀ ni Ibadan.

Awon onise ibi tunti gbe ise won de leyin ti won fi ipa ba omode obinrin kan lopo ni ipinoe Ondo, latari iwa buruku won fi oju ara obinrin omo naa ya.

A gbo pe oruko omo naa nj Oluwatosin Abosede, pe enikan wo omo naa lo si soobu kan ti o si fi ipa ba lopo. Won fi esun kan awon olopaa pe won o jafara nipa isele naa nitori bi won se gbe omo naa lo si Irele General Hospital ni Irele local government area ni Ondo, won pada lesekese.

Won ni won ni lati se ise ebi lati ran oju ara omo naa pada.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…