Rita Dominic ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Gbajumo osere onitiata, Rita Dominic, n se ayeye ojo ibi odun metalelogoji lonii July 12, 2019. O gbe aworan ara re ti o rewa si ori Instagram lati se ayeye ojo ibi naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…