Home Entertainment Mo p’arọ́ nípa ikú mí nítorí àwọn èèyàn ò rí ẹwà inú tálẹ́ńtì mi.

Mo p’arọ́ nípa ikú mí nítorí àwọn èèyàn ò rí ẹwà inú tálẹ́ńtì mi.

Gbajumo akorin omo Naijiria, Skibii, ti soro nipa iro to pa nipa iku re ni odun 2015, o so eyi ninu ifoworowanilenuwo pelu osise ori redio Dotun.

Leyin odun kan ti o kuro labe Five Star Music ni 2018 lati da ile ise orin tie sile, Skibii ni oun paro nipa iku oun nitori oun ti setan fun gbogbo nnkan amo awon eeyan o ri ewa ini talenti oun.

O ni, “mo ti setan fun eyi, fun gbogbo nnkan. Nnkan ti mo ro nipe awon eeyan o mo nnkan ti mo le se. Won o ri ew inu talenti mi. Nnkan pupo si n bo lona. Awon lo ni hiiti ni, emi gan o mo.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…