Home iroyin Ìṣe ẹlẹ́yàmẹyà ni láti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wón lóyún kúrò ní ilé ìwé kí wón sì fi àwọn ọkùnrin tó fún wọn lóyún sílè – Obìnrin àkọ́kọ́ Ìpínlẹ̀ Ekiti.

Ìṣe ẹlẹ́yàmẹyà ni láti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wón lóyún kúrò ní ilé ìwé kí wón sì fi àwọn ọkùnrin tó fún wọn lóyún sílè – Obìnrin àkọ́kọ́ Ìpínlẹ̀ Ekiti.

Aya Gomina ipinle Ekiti, Arabinrin Bisi Fayemi, ti so pe ise eleyameya ni lati ma a le awon obinrin akekoo ti won loyun kuro ni ile iwe ki won si fi awon okunrin ti won fun won loyun sile ni ile iwe.

Ninu ipade pelu awon iyawo awon adari ati ofisa idagbasoke agbegbe ti awon local government councils merindinlogun to wa ni ipinle naa ni Arabinrin Bisi Fayemi ti so eyi.

O ni gbogbo obinrin, kii ba se agba tabi omode lo ni eto si iwe kika.

Obinrin akoko naa ni orisirisi ijiya esun ni awon obinrin ti o ba loyun ma n dojuko, lara re àìní anfani lati lo si ile iwe. O si ti fihan pe ijoba na se setan lati se ofin ti ko ni si iyasoto ninu lati daabo anfani awon omo.

O so pe ipolongo nipa pataki eto awon omo paapaa julo awon omo obinrin ma waye ni osu ti n bo.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…