Home Entertainment Èéfín mọ́nọ́mọ́nọ́ ti pa mọ̀lẹ́bí méje.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 12, 2019

Èéfín mọ́nọ́mọ́nọ́ ti pa mọ̀lẹ́bí méje.

Isele ibanuje kan ti waye ni Elele, Ikwerre local government area ni ipinle Rivers, leyin ti eefin monomono(generator) ti pa molebi meje.

Awon ara ile won lo fura nigba ti ko ri enikeni jade lati inu yara won, ti o si je pe awako ti o man ji jade laraaro nile ni baba won.

Gege bi eni ti isele naa soju re se so, o ni isele naa waye ni Too Much Money Estate, Elele Town. Awon molebi naa si baba, iya, awon omo won okunrin merin ati omo won obinrin kan. Won ni ri oku won ni aaro Thursday leyin ti won tan monomono(generator) won moju ti eefin naa si gba emi won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…