Home orisiirisii Àwọn olè ti lọ jà ní ilé àwọn obìnrin ní Yunifásítì ti Ibadan.
orisiirisii - Orisirisi - July 12, 2019

Àwọn olè ti lọ jà ní ilé àwọn obìnrin ní Yunifásítì ti Ibadan.

Awon ole ti lọ ja ni Obafemi Awolowo Hall of residence(AWO) ni Yunifasiti ti Ibadan ni aaro oni July 12.

Gege bi awon akekoo ile iwe naa se so, awon ole ti won wa to mewaa, won wa ni ago kan ooru, won si wa nibe fun wakati meji.

Won ni awon oluso won ti wa ye won ninj yara won ni ago mokanla ale, ko pe si igba ti won lo ni won gbo ti eeyan n kolekun, won si ro boya awon oluso won lo pada wa, won si ṣi ilekun fun awon ole naa.

Awon akekoo bii márùn-ún ni won farapa, awon ole naa si ko awon nnkan ini won bii foonu ati laptop lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…