Home Entertainment AFCON 2019: Nigeria ma dojúkọ Algeria ní semi-final.

AFCON 2019: Nigeria ma dojúkọ Algeria ní semi-final.

Semi final Africa Cup of Nations 2019 ma waye laaarin West Africa ati North Africa.

Awon Super Eagles Nigeria ma dojuko Algeria ninunsemi finals, Senegal yoo si dojuko Tunisia.

Se egal yoo dojuko Tunisia ni 30 June Air Defence Stadium ni 14 July ni ago márùn-ún irole, ki Nigeria to fojuko Algeria ni ojo naa ni Cairo International Stadium ni ago mejo ale.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…