Home iroyin Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.

Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.

Won ti pa akekoo oniwe eri Phd ti o n je Thomas Orhionsefe Ewansiha ni Malaysia. Thomas si je olomo meji. Oga imigiráṣọ̀n ni won pa a si leyin fi awon imigirason mu fun esun ti ko mo nnkankan nipa re.

Isele naa waye leyin ti awon imigirason lo si Amapuri lati lo ko awon ti won ko ni iwe igbeelu. Bi o tile je pe oloogbe naa ni iwe igbeelu, won ko won awon ti ko ni iwe naa, won si ko won lo si kaanpu dipotason ni Jalan Duta. Nibi ti oloogbe naa ku si. Isele naa ti fa ìjì jangbara ni embasi Naijiria ni Malaysia.

Gbajumo akorin Daddy Showkey si ti da si isele naa, o ni ninu ifiranse ti oun ri, kii se igba akoko ti awon osise embasi Naijiria ma kawo ma wo iru isele bayii kimo ma sele ki awon omo Naijiria ni Malaysia. Won si be oun pe ki oun gbe ifiranse yii si ori afefe ki iru isele bayii ma tun waye mọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…