Home iroyin Ọmọ ọdún márùndínlọ́gbọ̀n ti fi ipá bá ìyá ọdún àádọ́rin lòpọ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 11, 2019

Ọmọ ọdún márùndínlọ́gbọ̀n ti fi ipá bá ìyá ọdún àádọ́rin lòpọ̀.

Awon olopaa ipinle Imo ti n wa arakunrin kan ti n je Chudera Nwachukwu omo odun marundinlogbon, leyin ti o fi ipa ba anti re ti n je Imelda Nwachukwu omo odun aadorin lopo ninu soobu re ni Ogwa ni Mbaitoli local government area ni ipinle Imo.

Ajafeto, Harrison Emefiana Gwamnishu ni i so eyi fun LIB ninu iforowanilenwo, o ni isele naa waye ni ojo Monday July 8.

O ni, “ mama naa ao fun ni ojo Monday pe oun wa ni soobu oun nibi ti oun ti n ta bisiki ati awon worobo miiran nigba ti arakunrin naa wa ba oun lati soro nipa irinajao re lo si Owerri. O ni lojiji ni o ti oun ti oun si fori gba ti oun si sun lo. O ni nigba ti oun ji, ihiho ni oun ba ara oun ti oun si ri ato okunrin ni gbogbo ara oun. Oun si pariwo, àwon ara ilu si wa lati ran oun lowo.”

Emefiana ni lesekese ni awon ara ilu naa gbe iya naa lo si ile iwosan fun itoju, ibe si ni won ti oe oun. Won ti gbe ejo naa lo si ago olopaa ti Ogwa, won si ti bere si ni wa arakunrin naa tk ti salo.

Harrison ni ko si agbejoro ti o le duro fun arakunrin naa ni ile ejo nitori mama o wo aso to si ara sile. Iwa ika ti o ye idajo to tọ ni eyi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…