“Ọba ọkàn mi” – Joke Silva ń kí ọkọ rẹ̀ fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Agba osere onitiata, Olu Jacobs n se ayeye ojo ibi re , o pe odun metadinlogorin lonii, iyawo re, Joke Silva si ti ki ku ayeye ojo ibi lori instagram.
Iyawo re gbe aworan si ori instagram, o si ni “E yin oluwa logo…..ku ayeye odun metadinlogorin lonii Sir J. Ku emi re ko kun ninu àlàáfíà ati oro….The Quintisential Ovorawen…pelu ife pupo oba okan mi.”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…