Liz Anjorin ti k’ọ́lé tuntun.
Gbajumo onitiata ere Yoruba, Liz Anjorin ti ko ile tuntun ni ipinle Eko, o si ti gbe aworan ile naa si ori instagram.
Ile naa to wa ni Eti-Osa local government ni ipinle Eko, onsere naa ni oun fe fi pamo tele ni, amo nigba ti oun wa ri pe ni June/July ni gbogbo awon ile oun ma n pari, oun ni lati gbe eri naa sita fun gbogbo araye ri.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…