Home Entertainment Kò sí ààyè fún àwọn ọ̀rẹ́ mi láti pé ọkọ mí lórí ago rè,àyàfi lọ́jọ́ ìbí rẹ̀ – Funke Akindele-Bello.
Kò sí ààyè fún àwọn ọ̀rẹ́ mi láti pé ọkọ mí lórí ago rè,àyàfi lọ́jọ́ ìbí rẹ̀ – Funke Akindele-Bello.
Gbajumo osere onitiata Funke Akindele-Bello, ti so pe ko si aaye fun awon ore oun lati ma ba oko oun soro lori ago bi o ba se wun won.
Funke ti o je iyawo gbajumo olorin JJC Skillz t i won si bi ibeji ni odun to koja, ti so pe awon ore oun le pe oko oun ti o ba n se ojo ibi re tabi ti won ba pe oun lori ago ti ko lo. Ayafi nnkan meji yii, ko si aye fun won lati pe ago oko oun.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…