Home orisiirisii Gbogbo nnkan ti bàjẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Kwara – Gómìnà AbdulRazaq.

Gbogbo nnkan ti bàjẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Kwara – Gómìnà AbdulRazaq.

Gomina ipinle Kwara AbdulRahman AbdulRazaq ti kero pe ijoba ti o koja ti ba gbogbo nnkan je ni ipinle naa.

Gomina naa ti so pe won ba nnkan je debi pe yoo to opolopo odun ki won yomke tunse tan. O si ti ni ijoba oun yoo fi 11.2 bilionu naira sile lati fi tun awon ile iwe se. O si erongba eyi ni lati yo awon ile iwe naa kuro ninu ipo ti won wa.

O so eyi nigba ti o se komison fun ile ikawe tuntun ni Kwara State University (KWASU) ni Malete, ni Moro local government area ipinle naa. Tertiary Education Trust Fund(TETFUND) lo si pese owo ti won fi ko ile ikawe naa. Igbakeji gomina Kayode Alabi lo duro fun gomina, gomina ni: “gbogbi nnkan ti baje ni ipinke Kwara, yoo gba opolopo odun lati tun awon ibaje yii se, amo ti gbogbo wa ba pawopo yoo je aseyori. Iberepepe ni a o ti bere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…