Home orisiirisii Arábìnrin ọmọ Nàìjíríà ti kú lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ mẹ́rin tó jáde ilé ìwé.
orisiirisii - Orisirisi - July 11, 2019

Arábìnrin ọmọ Nàìjíríà ti kú lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ mẹ́rin tó jáde ilé ìwé.

 

Arabinrin omo Naijiria kan ti n je Fatima ti ku ni ojo Tuesday July 9, ose merin si igba ti o jade ile iwe giga.

Oloogbe Fatima jade lati ile iwe Bayero University Kano ni June 12, 2019. Ore egbon re obinrin ti n je Saadatu Ahmad lo gbe isele naa si ori Facebook, o ni osu die lo ku si ojo igbeyawo ologbee naa.

Ki olorun fi orun ke oloogbe naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…