Home Entertainment AFCON2019: Ààrẹ Buhari ti kí àwọn Super Eagles fún orí ire wọn.

AFCON2019: Ààrẹ Buhari ti kí àwọn Super Eagles fún orí ire wọn.

Ni ale ana ni awon Super Eagles na awon Bafana Bafana South Africa ni 2-1 ni Africa Cup of Nations ti n lo lowo ni Egypt.

Fun oriire naa, Aare Buhari ti ki awon Super Eagles fun oriire pe wonma bo si ipele ti o kan ninu African Cups of Nations 2019 ti n lo lowo ni Egypt.

Ninu gbolohun ti aare fi kale ti SA aare lori ori afefe,Femi Adesina towo bo, o ni oun ki awon Super Eagles fun oriire yii lori Bafana South Africa, oun si gbagbo gege bi awon ti o nifee ere idaraya naa se gbagbo pe o ku die ki awon Super Eagles tun gba kọọpu naa ni igba ekerin.

Aare Buhari tun so fun awon Suoer Eagles pe ki won ma i ti simi nitori o si ku ipele meji lati gba ogo won. Bee o so fun pe, awon omo Naijiria lapapo n gbadura fun won nitori gbogbo omo Naijiria pata ni oriire naa ma kan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…