Home orisiirisii Adarí ilé ìwé tí lé Àgùnbánirọ̀ kúrò ní ilé ìwé rẹ̀ nítorí kò gbà láti ba ní ìbásepọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 11, 2019

Adarí ilé ìwé tí lé Àgùnbánirọ̀ kúrò ní ilé ìwé rẹ̀ nítorí kò gbà láti ba ní ìbásepọ̀.

 

Adari ile iwe kan ti le agunbaniro obirin ti won ran si ile iwe re lati sin ile baba re fun odun kan nitori ko gba lati ba ni ibasepo.

Adari ile iwe naa so fun agunbaniro naa pe oun ma fun ni ile, oun si ma je ki ise naa rorun fun, fun odun kan ti o ma lo nibe, amo nitori agunbaniro naa o gba lati ba ni ibasepo, o le e, o si ko lati towo bo iwe re.

Enikan ti n je @di.zire lo gbe isele naa si ori instagram, o ni arakunrin naa ti leri pe oun ma so fun awon osise NYSC pe agunbaniro naa lo ni oun ko fe duro si ibi ti won gbe si(place of primary assignment PPA), iyen ile iwe tiẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…