Home iroyin Nàìjíríà ló ní iye ọmọ tí kò lọ sí ilé ìwé tó pọ̀ jù kárí ayé – UNESCO
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Nàìjíríà ló ní iye ọmọ tí kò lọ sí ilé ìwé tó pọ̀ jù kárí ayé – UNESCO

Gege bi UN’s cultural and education agency, UNESCO se so, Naijiria lo ni iye omo ki lo si ile iwe to poju kari aye.

O ni milionu mewaa omo Naijiria paapaa obinrin ni won ko losi ile iwe. Bi o tile je pe orile ede naa ni ofin to pon dandan ki awon omo maa lo si ile iwe, sibe pupo ninu won n toro bara loju titi tabi ki won se ise ti ko tọ.

Ijoba ti so pe won ti da eto sile ni odun 2016 lati ma fun awon akekoo ni ounje, ti o si wulo fun awon akekoo bi milionu mewaa, ti o si je ki won ma lo si ile iwe. Bi o tile je pe awon kan n se madaru bee ni won o se ooto pelu eto naa, ti ijoba n sise le lori lati yanju re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…