Home Entertainment Mo ma pa ọkùnrin tó bá fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ lójú ẹsẹ̀ – 9ice

Mo ma pa ọkùnrin tó bá fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ lójú ẹsẹ̀ – 9ice

Gbajumo akorin 9ice, ti da si awuyewuye ti lo lowo nipa ifipabalopo.

Ninu ifoworowanilenuwo ti onji pelu Goldmyne lo ti fi ifipabalopo we ole jija, o si fi pinu pe enikeni ti oun ba ka iru e mo lowo oun ma pa a lójú ese, o si ti dabaa ki awujo won ma pa iru eni be.

O ni awon oninobi po jaburata ti okunrin le ba ni asepo ti ko ni si oro ife ninu e.

O ni: “ ko si aye fun ifipabalopo. Omo po ni titi. Se iwo ko ni enu lati ko enu ife si obinrin ni? Se o ya were ni? Ti n ba ri iru ọkùnrin bee, mo ma pa a ni.

Ko ni da fun okunrin ti n fi ipa ba lopo, won o ni s’orire. Ti iwo ko ba ko enu ife si obinrin, pelu 5k, 10k, 15k o ma ri oninobi obinrin. Won po ni Ikeja. O ye ki won ma pa okunrin to ba fipabalopo.

O ye ki won sun won ni aye. Ifipabalopo buruju ole jija, awon eni ti won ba fipabalopo le ma ni alaafia ti peye ti aye, fun idi eyi, ki won ma pa iru eeyan bee.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…