Home orisiirisii Ilé ẹjọ́ ti fi bàbá tó fi ipá bá ọmọ rẹ̀ obìnrin lòpọ̀ sì ẹ̀wọ̀n ní Ekiti.
orisiirisii - July 10, 2019

Ilé ẹjọ́ ti fi bàbá tó fi ipá bá ọmọ rẹ̀ obìnrin lòpọ̀ sì ẹ̀wọ̀n ní Ekiti.

Ile ejo ni ipinle Ekiti, Ado Ekiti ti fi arákùnrin kan ti n je Basiru Adeyanju si ewon, leyin ti o fi ipa ba omo re obinrin odun metadinlogun lopo.

Adajo Oluwatoyin Abobunde lo da ejo naa leyin ti o gbo ejo lati enu awon mejeeji ti oro naa kan.

Adajo naa si sun idajo ejo naa si October 2,2019, lati le gbe ejo si.

Adeyanjuti n gbe ni Ado Ekiti, ni won fi esun kan pe o fi ipa ba omo naa lopo, ati pe o gbiyanju lati ba lopo. Esun mejeeji ti won fi kan niyen.

Sibe, Adejanyu ni oun ko jebi esun ti won fi kan oun.

Attorney General ipinle Ekiti, Olawale Fapohunda, to dari egbe ti o n sise lori ejo naa ti pe Dokita Olasende Temitope lati se ayewo lori omo naa, ti o si so pe looto ni won fi ipa ba omo naa lopo.

Dokita Temitope ni won gbe omo wa fun ayewo leyin ti won ba lopo ni September 11,2017, o ni esi ayewo naa ni pe omo naa ti n ba baba re gbe fun odun meji leyin ti iya ati baba ti ni ìpínyà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…