Home orisiirisii Ilé ẹjọ́ ti fi àwọn onípanṣágà ọgbọ́n sí ẹ̀wọ̀n ní Ìpínlẹ̀ Jigawa.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Ilé ẹjọ́ ti fi àwọn onípanṣágà ọgbọ́n sí ẹ̀wọ̀n ní Ìpínlẹ̀ Jigawa.

Ile ejo ti fi awon ononobi ogbon ti Jigawa Hisbah command ko ni aaro ojo Satide si ewon osu meta fun pansaga.

Awon onipansaga ti won ko yii ti ni awon jebi esun ti won fi kan awon, o adajo Sadam Habib, si ti ni ki onikaluku won san egberun márùn-ún naira gege bi itanran(fine).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…