Home orisiirisii EFCC ti gbé babaláwo irọ́ ní Ìbàdàn.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

EFCC ti gbé babaláwo irọ́ ní Ìbàdàn.

The Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti Ibadan ti gbe babalawo iro kan ti nje Fatai Olalere Aliu, lanaa Tuesday July 9. Fatai ma n dibo bi babalawo lati gba awin eeyan ti won gbe isoro won lo ba.

Gege bi EFCC se so, won mu Aliu ni ile re ni Kisumu Estate ni Odo-ona Elewe ni Ibadan, ipinle Oyo. Ki won to lo gbe, won ti n gbo orisirisi iroyin lati odo awon eeyan nipa bi o se n gba won pelu owo ribiti. Won fi esun kan an pe o ma gba owo lowo awon eeyan pe oun ma so owo naa di ilopo meji iye owo naa, amo apo ara re ni owo naa ma lo.

Leyin iroyin ti won gbo, EFCC ya lo si ibudi agbara rr ti wo wa ninu igbo kijikiji kan ni Ibadan-Ijebu-Ode Expressway ati agbegbe Kobomoje ni ilu naa. Won ri orisirisi nnkan ti n bani leru nibe.

Lara awon nnkan ti won gba lowow re ni oko bogini meta, Toyota Corolla meji ati Honda pilot kan. Bee ni won gba ile nla meta lowo re ati awon iwe ilẹ̀.

Won n se ijabo fun lowo ni Zonal ofisi won ni Ibadan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…