Home orisiirisii Àwọn ọ̀mọ̀ọ̀lé ti fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ láti fi ìyà jẹ ẹ ní Ìpínlẹ̀ Ekiti.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Àwọn ọ̀mọ̀ọ̀lé ti fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ láti fi ìyà jẹ ẹ ní Ìpínlẹ̀ Ekiti.

Iwa ibaje ti n gba gbogbo awujo kan tunti wayi ni ipinle Ekiti, leyim awon omoole(brick layer) ni Ilejemeje ni ipinle Ekiti fi ipa ba obinrin ti o wa laaarin lopo lati fi iya je e nitori ko je ise ti won ran.

Gege bi@juiciesofjays se so lori Twitter, o ni arabinrin naa n sise naa nitori ati bo awon omo nitori omuti paraku ni oko re, o ni awon omoole naa ma n ran obinrin naa ni ise bi o ba se wun won.

O ni lanaa, arabinrin naa ko lati je ise fun won, bi won se fi ipa ba lopo lati fi iya je e nitori ko jise fun won. O ni awon ijoba ipinle Eko ti gno nipa isele naa, won si ti da si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…