Home orisiirisii Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn ajínigbé tí wón jí olùkọ́ ní OAU gbé.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn ajínigbé tí wón jí olùkọ́ ní OAU gbé.

Awon olopaa ipinle Osun ti mu awon ajinigbe ti won ji Professor Olayinka Adegbehingbe ti o je orthopaedic surgeon ni Obafemi Awolowo University, Ile-Ife gbe.

Ni ojo Sunday, May 5 ni awon Fulani ti won sin eranko ji Adegbehingbe ji nigba ti o n lo si Ile-Ife lati Eko, ti won si 5.45 milionu naira ki won to fi sile.

Komisiona olopaa ti ipinle Osun, Abiodum Ige, lo gbe arakunrin naa, Usman Ladan sk waaju awon oniroyin lanaaa, wi pe Professor Adegbehingbe lo da okan lara awon ti ji gbe mo. Oloye olopaa ni won mu okan lara awon odaran naa ni Ikire nibi to ti n ein gberegbere, won si mu awon meji to ku ni agbegbe Iwo fun esun miiran.

Awon okunrin ti won fura si naa ni, Samaila Gede lati Katsina, Kemu Rejuli lati Niger Republic ati Jubril Mohammed lati Katsina. Won si ba orisirisi oogun lara won.

Komisona ti ni leyin ti won ba oari iwadii, won ma fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…