Home orisiirisii Àwọn ọlọ́kadà méjì ti kọlu ara wọn ní Lagos-Ibadan Expressway.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Àwọn ọlọ́kadà méjì ti kọlu ara wọn ní Lagos-Ibadan Expressway.

Awon olokada meji ti koku ara won ni opopona Lagos-Ibadan.

Awon mejeeji ni awon irin titi naa ti fa ipalara fun ni ori won.

Isele naa waye ni aaro oni ojo Wednesday, ijamba naa o si kan oko kan kan, nitori won wọ awon mejeeji si egbe kan, oko kan kan o si duro sibe.

Isele naa waye leyin ti awon ti n wa oko ni titi naa koja lara awon ti n tun titi naa se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…