Home orisiirisii Àwọn àgbájọ èèyàn ti pa arákùnrin kan fún ẹ̀sùn nǹkan tí kò mọ̀ nípa rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 10, 2019

Àwọn àgbájọ èèyàn ti pa arákùnrin kan fún ẹ̀sùn nǹkan tí kò mọ̀ nípa rẹ̀.

Isele buruku kan ti waye ni ojo Monday ni ipinle Eko, leyin ti awon eeya. fi esun kan arakunrin kan pe o ji foonu, ti ko si mo nnkan kan nipa re. won si na an titi emi fi bo lara re.

Agbegbe Bodore ni Ajah ni isele naa ti waye, leyin ti Olamide Omolede omo odun mejilelogun lo fi owo ṣaaji foonu re ni soobu kan ni agbegbe naa.

Arabinrin ti o ni won ji foonu oun lo ko awon agbero wa, ti won si naa arakunrin naa titi emi fi bo lara re, ti won si ju oku re sinu osa.

Eni ti isele naa waye loju re so fun Premimum Times pe, won koko mu akarinku naa lo si soobu ti won ni won ti ji foonu naa ni Iyalaye ni ihoho, ki won to luuu titi emi fi bo lara re.

O ni: “ leyin ti won luu pa, won ju oku re sinu osa, awon ti n gbe ni agbegbe naa sanwo fun awon Egun lati ba won wa oku naa sina. Aaro oni ni won gbe oku naa sita lati inu omo.”

Won pada ri foonu naa lowo omo eni ti o ni Omolede ji foonu oun, Baba omo naa ti ofi idi eri isele naa mule, Francis Omolede ni won ti fa arabinrin ati awon agbero naa le olopaa lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…