Arákùnrin tí ń wa ọ̀kadà ti pa ara rẹ̀ ní Eko.
Arakunrin ti n wa okada ti pa ara re nitori gbese ni Shoretire St ni agbegeb Agege ni ipinle Eko.
Iroyin ni arakunrin naa ti n je Ahmed, ti bi omo meta. Won ni bi o se de lati ibise ni o wo yara re ti o si pokun so.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…