Home Entertainment Yvonne Jegede ti ṣàlàyé ìdí tí ó ṣe wun òun kí òun dá wà.

Yvonne Jegede ti ṣàlàyé ìdí tí ó ṣe wun òun kí òun dá wà.

Gbajumo osere onitiata, Yvonne Jegede ti igbeyawo oun ati Olakunle Abounce Fawole daru ni osu die seyin, ti so nnkan ti eeyan le se lati ri ife oun nitori o ti mo oun lara ki oun ma da wa.

O si lori instagram pe o wun oun lati da wa ki oun le ni agbara lori idajo oun, ati pe ki eeyan to le ri ife oun, o ni lati ni imo gidi ju oun lo.

O ni;

Mo nifee ki n ma dawa
Ma ni agbara lori oro aye mi
Fun idi eyi, lati le ri ife,
Wawi re ninu aye mi, gbodo tu mi lara ju ki emi nikan da wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…