Home orisiirisii Wọ́n ti rí òkú akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà lẹ́yìn ọkọ̀ rẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Cyprus.
orisiirisii - Orisirisi - July 9, 2019

Wọ́n ti rí òkú akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà lẹ́yìn ọkọ̀ rẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Cyprus.

Leyin ojo die seyin ti won ti n wa akekoo omo Naijiria, Obasanjo Adeola Owoyale, won ti ri oku re leyin oko re ni Nicosia schools road, Northern Cyprus.

Ararkunrin naa je omo odun metalelogbon ni ile iwe Cyorus International University, o kuro nile ni July1,2019, won si bere si ni wa. Ayewo akoko ti won se nibi ti won ti ba oku re fihan pe apa nla kan wa ni ara re.

Won ti gbe oku re lo si Nicosia Burhan Nalbantoglu State Hospital, won si ma se ayewa nipa nnkan to fa iku re. Won si ti n se iwadii nipa nnkan to fa iku re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…