Home iroyin Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ arákùnrin kan tó jí Àgùnbánirọ̀ gbé tí ó sì fipá bá lòpọ̀. Owo awon olopaa ipinle Imo ti te arakunrin kan ti nje Chukuemeka Eze, fun esun pe o ji agunbaniro obinrin omo odun metadinlogbon gbe, o fi ipa ba lopo, o si pa a, leyin bi ose kan si igba ti o ma pari agunbaniro re. Owo ti te arakunrin naa pelu awon mokandinlogun ti won ma n sise ibi bii ajinigbe, ole jija, apaniyan ati lilo awon omode lona ti ko tọ. Chukuemeka Eze ti jewo pe oun pa Lilian Ngbawa, oun si fi ipa ba lopo. Agbegbe Mgbidi ni Oru West council area ni Lilian ti n sin ile baba re ki o to pade iku aitojo yii. Arakunrin naa mu awon olopaa lo si inu igbo nibi ti won ti ba oku Lilian, leyin ti Chukuemeka mu foonu re, eyi ti o fa akoba fun. Agbenuso awon olopaa, Frank Mba so fun awon oniroyin pe leyin ti won ba ti pari iwadii, arákùnrin naa yoo fi oju ba ile ejo.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 9, 2019

Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ arákùnrin kan tó jí Àgùnbánirọ̀ gbé tí ó sì fipá bá lòpọ̀. Owo awon olopaa ipinle Imo ti te arakunrin kan ti nje Chukuemeka Eze, fun esun pe o ji agunbaniro obinrin omo odun metadinlogbon gbe, o fi ipa ba lopo, o si pa a, leyin bi ose kan si igba ti o ma pari agunbaniro re. Owo ti te arakunrin naa pelu awon mokandinlogun ti won ma n sise ibi bii ajinigbe, ole jija, apaniyan ati lilo awon omode lona ti ko tọ. Chukuemeka Eze ti jewo pe oun pa Lilian Ngbawa, oun si fi ipa ba lopo. Agbegbe Mgbidi ni Oru West council area ni Lilian ti n sin ile baba re ki o to pade iku aitojo yii. Arakunrin naa mu awon olopaa lo si inu igbo nibi ti won ti ba oku Lilian, leyin ti Chukuemeka mu foonu re, eyi ti o fa akoba fun. Agbenuso awon olopaa, Frank Mba so fun awon oniroyin pe leyin ti won ba ti pari iwadii, arákùnrin naa yoo fi oju ba ile ejo.

Owo awon olopaa ipinle Imo ti te arakunrin kan ti nje Chukuemeka Eze, fun esun pe o ji agunbaniro obinrin omo odun metadinlogbon gbe, o fi ipa ba lopo, o si pa a, leyin bi ose kan si igba ti o ma pari agunbaniro re. Owo ti te arakunrin naa pelu awon mokandinlogun ti won ma n sise ibi bii ajinigbe, ole jija, apaniyan ati lilo awon omode lona ti ko tọ.

Chukuemeka Eze ti jewo pe oun pa Lilian Ngbawa, oun si fi ipa ba lopo. Agbegbe Mgbidi ni Oru West council area ni Lilian ti n sin ile baba re ki o to pade iku aitojo yii.

Arakunrin naa mu awon olopaa lo si inu igbo nibi ti won ti ba oku Lilian, leyin ti Chukuemeka mu foonu re, eyi ti o fa akoba fun.

Agbenuso awon olopaa, Frank Mba so fun awon oniroyin pe leyin ti won ba ti pari iwadii, arákùnrin naa yoo fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…