Home iroyin Iná ti gbé àwọn ọkùnrin méjì ní Ìpínlẹ̀ Kaduna.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 9, 2019

Iná ti gbé àwọn ọkùnrin méjì ní Ìpínlẹ̀ Kaduna.

Isele buruku kan ti waye ni tiyi NNPC ni ipinle Kaduna lonii,leyin ti ina gbe awon okunrin meji nibi ti won ti n sise lori ina titi.

Eni ti isele naa sele loju re ni, igba ti ti won n sise lowo ni waya kan ti ina wa kara re kan afara onirin ti won n lo ti ina naa si gbe won. Won ti fi isele naa to awon olopaa leti ki won le palemo awon oku naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…