Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìjà tí wáyé ní pápá ọkọ̀ -òfuurufú ti Abuja.

Ìjà tí wáyé ní pápá ọkọ̀ -òfuurufú ti Abuja.

Ija ti be sile ni Nnamdi Azikiwe Airport ni Abuja.

Gege bi iroyin se so, a gbo pe iya naa waye laaatin awon ti won fe wo oro ofurufu ti Airpeace, awon ti n lo si Enugu atinawon ti n lo si Eko n ja si eni ti o ma koko wo ọkọ̀.

Eni ti isele naa soje re ni, awon ti won fe ba oko ofurufu Airpeace ti wa ni papa oko-ofurufu lati ago mewaa aaro ti o je igba ti o ye ki oko won gbera, ti won si da won duro titi di ago merin koja isejun ogbon irole sibe ti won o tii mo ago ti oko won ma gbera, eyi lo fa ibinu ti won ko gba ki enikeni lo wo oko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…