Home iroyin Ẹ má dá sí bí mo ṣe fẹ́ yan àwọn Kọmíṣọ́nà mi – Ortom si PDP

Ẹ má dá sí bí mo ṣe fẹ́ yan àwọn Kọmíṣọ́nà mi – Ortom si PDP

Gomina Samuel Ortom ti ipinle Benue ti so fun egbe oloselu re PDP pe ki won ma dasi bi oun se fe yan awon komisona oun.

Ninu ipade egbe oloselu PDP ti won se ni gbogan Banquet ni ile ijobe ni Markurdi ni Ortom ti so eyi.

Gomina si ti kilo fun awon ti o fe yan pe ti won mu ise ni won pataki, o se e se ki won ja iwe gbelee fun won lojo keji ti won ba bere ise.

Gomina naa si ti iede pe komisona marundinlogun ni oun ma yan lati zoonu meteeta ipinle naa.

Ortom ti se ileri pe oun o ni se oju isaaju si enikeni, bakan naa ni oun se ma si gbogbo won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…