Àwọn ọmọ ti jí bàbá wọn gbé ní Ìpínlẹ̀ Imo.
Owo olopaa ti te awon omo iya ti won n je, Chinazea ONwoju ati Emeka Ejike, pelu eniketa eon Emmanuel Sunday, leyin ti awon omo meteeta gbiyanju lati ji baba won ti n je Louis Njoku omo odun mejidinlaadorun gbe.
Emmanuel ti o je orekunrin Chinaza ti ni leyin ti awon ba gba owo ti won fe ri nidii ajinigbe yii tan, oun a fi ipin oun san owo ori Chinaza.
Agbenuso awon olopaa, PRO, Frank Mba ni awon Anti-Kidnapping Unit ti ipinle Imo ni won mu won ni June 29 leyin ti enikan fi to won leti.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…