Home Entertainment 2019 BBNaija: Àwọn tí ó ṣe é ṣe kí wọ́n lọ sí ilé ní ọ̀sẹ̀ yìí,Tacha, Mercy àti àwọn mẹ́ta miiran.

2019 BBNaija: Àwọn tí ó ṣe é ṣe kí wọ́n lọ sí ilé ní ọ̀sẹ̀ yìí,Tacha, Mercy àti àwọn mẹ́ta miiran.

Leyin bi ose meji ti won bere Bbnaija ti odun 2019, eyi ti o je okan lara ere idaraya ti o ma n dun mo awon omo Naijiria ju. Eyan meji ti lo si ile laarin awon mokandinlogun ti won jo bere ere idaraya naa.

Ni ojo Sunday ti o koja ni Isilomo ati Avala lo si ile, leyin ti won ni koinsi to kere ni ile naa.

Ni bayii won ti yan e marun-un ti o se e se ki won lo si ile ni Sunday ti n bo. Awon ti won si yan ni Tacha,Kimoprah,Frodd,Sir Dee ati Ella.

Amo nigba ti won se ere idaraya ni aarin ose, Frodd ni anfaani lati yo ara re ki o si fi elomii dipo ara re. O si yo ere re, o fi Mercy dipo ara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…