Home orisiirisii Wọ́n ti mú akẹ́kọ̀ọ́ ní ilè ìwé FUTO níbi tó ti ń gbìyànjú láti fi ìkejì rẹ̀ ṣ’owó.
orisiirisii - Orisirisi - July 8, 2019

Wọ́n ti mú akẹ́kọ̀ọ́ ní ilè ìwé FUTO níbi tó ti ń gbìyànjú láti fi ìkejì rẹ̀ ṣ’owó.

Won ti mu akekoo kan ni ile iwe Federal University of Technology, Owerri(FUTO) nibi to ti n gbiyanju lati fi ikeji re sowo.

Akekoo naa je akekoo ni eka Biologucal Science, won mu ni ile awon akekoo, Bliss Mansion ni Umuchima ni ipinle Imo. Nigba ti won mu lo ka pe oun fe fi ikeji oun se owo ki jibiti ti oun n se (yahoo yahoo) le m lo dada.

Enikeji re to fe fi sowo ni orukonre n je Daniel, oun naa je akekoo ni eka Biological Science, Daniel ni o pe oun ninale patapata pe pun fe wa sun lodo oun pe awon olopaa n da oun laamu, o ni nigba to de o ni ebi n panoun pe ki oun wa nnkan ti oun le je ra fun oun ni ale naa.

Daniel ni emi kan ni oun fi lo nitori agbegbe awon soro rin ni ale, o ni igba ti oun se ounje naa fun tan ko je e, o ni oun fi nnkan si pe oun o si fi nnkan si. Nigba to se die, o wa ba oun pe orin ti oun gba n di orun oun.

Ko pe lo tun wa ba oun oe kilode ri oun o se sun, oun si ni oun ko ti kun oun, bomse bere si ni lu oun ti oun si kepe iranlowo ti awon ara ile oun si gba oun sile.

O ni o so fun oun oe oun fe lo oun fun owo ni, omo agbegbe okunkun ni amo o ma n fi awon se owo ni.

Won ti fa a le awon agbofinro lowo, iwadii si n lo lori oro naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…