Pásítọ̀ tí fi ipá bá ọmọ ọdún márùndínlógún lòpọ̀, ó sì fún lóyún.
Awon olopaa ago olopaa igando ni ipinle Eko ti gbe arakunrin kan pasito Pope Paul ti n gbe ni No 10/11 street Ishuti Road Egan Igando fun esun pe o fi ipa ba omo odun marundinlogun lopo ti o si fun loyun.
Ninu gbolohun ti agbenuso fun olopaa ipinle eko Bala Elkana fi kale, o no iya omo naa lo wa fi ejo sun ni ago olopaa ni July 2, o ni August 2017 ninwon mu omo naa wa si eko lati wa ba pasito ati iyawo re gbe.
O ni, ni June 2018 ni oun sakiyesi pe omo naa ti loyun, nigba ti oun si bere lowo re pe ta lo fun loyun, o daruko pasito naa.
Bala ni ninu gbolohun ti omo naa fi kale, o ni lati January 2018 ni pasito naa ti ma n ba ni asepo titi to fi loyun.
O ni oun fi oyun naa bi omo obinrin ni April 2019.
Bala ni pasito naa ma to fi oju ba ile ejo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…