Home iroyin Gómìnà Obaseki ti ń béèrè nípa kọ́ńtírátìì ilé ìwòsàn lọ́wọ́ Adams Oshiomhole.

Gómìnà Obaseki ti ń béèrè nípa kọ́ńtírátìì ilé ìwòsàn lọ́wọ́ Adams Oshiomhole.

Gomina Godwin Obaseki ti da igbimo sile lati se iwadii nipa kontiratiii lati pese ohun elo fun kiko Benin Central Hospital, ti ijoba Adams Oshiomhole gbe sile.

Won da igbimo naa sile lati se ayewo boya won tele ilana to ye fun kontratii ti alaga APC gbe kale, paapaa julo lati wo didara awon ohun elo ati lati se ayewo nipa bi won se n ra awon ohun elo naa.

Agbenuso fun Gomina Obaseki, Cruise Osagie ninu gbolohun ti o fi kale, so pe leyin opolopo ipe pe ki Ijoba ipinle Edo se ayewo awon kontiratii ti won run owo iyebíye si, ti awon purojeti naa ko dara to lebe akoso Adams Oshiomhole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…