Home Entertainment Ẹ̀gbọ́n Davido, Adewale Adeleke ti ní kí ọ̀rẹ́ bìnrin rẹ̀ fẹ́ òun.

Ẹ̀gbọ́n Davido, Adewale Adeleke ti ní kí ọ̀rẹ́ bìnrin rẹ̀ fẹ́ òun.

Egbon gbajumo akorin, Davido, Adewale Adeleke ti ni ki orebinrin re, Kani, fe oun, o ti ki oruko sii lowo, o si ku ki won bere si ni se ipalemo igbeyawo.

Adewale Adeleke mu orebinrin re lo si ori oke ile kan, o si kunle ese kan o si bere boya o me fe oun pelu ododo ti o rewa.

Kani sese gba iwe eri Masters ni Georgetown University, Adeleke si ni ojo naa ni ojo to dara ju ni igbesi aye oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…