Home Entertainment Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.

Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.

Aworan igbeyawo baba ati iya agbalagba yii waye ni ipinle Zaria, igbeyawo won naa si fun olopopo awon eeyan ni ireti.

Arakunrin kan ti n jd Chinecherem Ebubechi lo gbe aworan naa si ori Facebook, oko je omo doun metalelaadota Evengelist Mattew Owojaiye, iyawo je omo odu. Metalelogota Abosede Ayobola.

Gege bi Chinecherem se so, igbeyawo yii ni igbeyawo won akoko, won pade ara won odun aadorin seyin. Oko naa si ni ki arabinrin naa fe oun, amo o ko jale. Leyin opolopo odun, won tun pade ara won, won si ri pe awon o tii jo ninkko ati iyawo. Won si gba lati fe ara won.

Won si igbeyawo naa ni Living Faith Church ni Zaria pelu awon ore ati molebi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…