Home orisiirisii Arákùnrin kan ti fi ipá bá ọmọ ọdún mẹ́rìnlá lòpọ̀ nínú ilé àkọ́kù.
orisiirisii - Orisirisi - July 8, 2019

Arákùnrin kan ti fi ipá bá ọmọ ọdún mẹ́rìnlá lòpọ̀ nínú ilé àkọ́kù.

Awon olopaa ipinle Eko ti gbe arakunrin kan ti n je Aliyu Ali Mohammed, fun esun pe o fi ipa ba omo odun merinla loponinu ile akoku ni Peace Estate.

Ninu gbolohun ti agbenuso olopaa, Bala Elkana, ni won gbe Aliyu leyin ti arakunrin kan ti n je Harrison Chukwereuke, lo ri i nibi ti o ti n ba omo na lopo ni ojo Tuesday July 2. Harrison si lo fi ejo sun ni ago olopaa ti Iba. Awonnolopaa si lo gbe, o si wa ni ago olopaa lowo.

O ma to fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…