Home orisiirisii Arábìnrin ti kú lọ́jọ́ ìgbéyàwó rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 8, 2019

Arábìnrin ti kú lọ́jọ́ ìgbéyàwó rẹ̀.

Arabinrin kan ti oruko re n je Pearl Sedinam Lulu, ti fi awon molebi re sinu iponju ati ibanuje leyin to je olorun nipe ni ojo igbeyawo re, agbegbe Volta Region ni orile-ede Ghana ni isele naa ti waye.

O ye ki igbeyawo ibile si orekunrin re ojo pipe, Mawufemor Kosi Wampah, waye ni ojo Friday July 5 2019, ki won si se igbayawo soosi ni ojo Satide July 2019.

Lulu kero ori fifo ni aaro ojo igbeyawo ibile won, won si gbe lo si ile iwosan nibi ti o dake si.

Okan lara awon molebi re ni o fi idi eri isele naa mule, o ni Pearl gba ipe lori ago re lati odo ore re ni aaro ojo naa, ki o kero ori fifo ti o fa iku re. O ni awon ko ti mo nnkan ti ore re naa so fun lori ago nipa to pe e.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…