Home iroyin Àgùnbánirọ̀ ti fi òògùn p’ẹ̀fọn (sniper) pa ara rẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 8, 2019

Àgùnbánirọ̀ ti fi òògùn p’ẹ̀fọn (sniper) pa ara rẹ̀.

Agunbaniro ti won gbe lo si Oshogbo ni ipinle Osun lati sin ile baba re ti ku, leyin ti o fi oogun p’efon (sniper) si inu irun e lati fi pa ina(lice).

Ayomikun Juliana to je giraduati ile iwe Tai Solarin University of Education, ri ina ninu irun re leyin ti o lo si odo onidiri lati se irun re, nigba to ri ina na, loba fi oogun p’efon (sniper) si irun re o si fi ora bo o, o si sun lo.

Won ba ninubyara re lojo keji to wa lenu ese kan aye, ese kan oru, won si sare gbe lo si ile iwosan nibi to ku si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…