Home iroyin Arákùnrin ti fi ipá bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀, ó sì ṣ’ẹ́yún fun.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 7, 2019

Arákùnrin ti fi ipá bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀, ó sì ṣ’ẹ́yún fun.

Awon olopaa ipinle Delta ti gbe arakunrin kan ti o ma n fun omo re omo odun marundinlogunni oogun, yoo si fi ipa ba lopo bee si ni o tun ma seyun fun. Oun ati iyawo re si ni won jomma we iwa buruku yii.

Omo naa di iyawo baba re nigba akoko ti baba re ba ni ibasepo ti o si wa ni omo odun mewaa.

Ajafetoo Gwamnishu Harrison ni o fi olopaa gbe awon obi omo naa, o ni won ma foju ba ile ejo ni ojo Monday June 8 odun 2019. Omo naa n gba itoju lowo.

Ibo wa ni ile aye n lo bayii, ki olorun elédùmarè ma a fi iso e so wa o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…