Home iroyin Arákùnrin ọmọ Nàìjíríà kan ti s’aláìsí ní orílẹ̀ èdè Malaysia.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 7, 2019

Arákùnrin ọmọ Nàìjíríà kan ti s’aláìsí ní orílẹ̀ èdè Malaysia.

Arakunrin omo Naijiria kan ti n je Charles, ti n gbe ni Malaysia ti salaisi leyin ti awon imigiráṣọ̀n wa si ile won, nibi ti o ti n sa kiri ni o fo bole lati oke ti o si gbemi mi.

Nigba ti awon olopaa imigiráṣọ̀n wa si ile re ni Kajang, Selangor lati ko awon ti won ko ni iwe igbeelu ni Charles fo bole lati oke kefa si isale ti o si gbemi mi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…