Home iroyin Arakunrin omo Naijiria kan ti n je Charles, ti n gbe ni Malaysia ti salaisi leyin ti awon imigiráṣọ̀n wa si ile won, nibi ti o ti n sa kiri ni o fo bole lati oke ti o si gbemi mi. Nigba ti awon olopaa imigiráṣọ̀n wa si ile re ni Kajang, Selangor lati ko awon ti won ko ni iwe igbeelu ni Charles fo bole lati oke kefa si isale ti o si gbemi mi.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 7, 2019

Arakunrin omo Naijiria kan ti n je Charles, ti n gbe ni Malaysia ti salaisi leyin ti awon imigiráṣọ̀n wa si ile won, nibi ti o ti n sa kiri ni o fo bole lati oke ti o si gbemi mi. Nigba ti awon olopaa imigiráṣọ̀n wa si ile re ni Kajang, Selangor lati ko awon ti won ko ni iwe igbeelu ni Charles fo bole lati oke kefa si isale ti o si gbemi mi.

Awon olopaa ti gbe arabinrin kan ti n je Mariya, fun esun pe o gun egbon re pa leyin ti won jo ni àríyànjiyàn ni agbegbe Badawa ni Nassarawa ni ipinle Kano.

Iroyin ni, loju ese ni okunrin naa gbemi mi nitori o so eje pupo nu.

Won ni nnnkan to fa àríyànjiyàn ni pe, egbon ni ki aburo re ma se igbeyawo aláriwo, eyi lo faa ti oburo fariga ti o si fi ibinu gun egbon re pa ti emi fi bo lara re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…