Home Entertainment UNILORIN ò tíì rí orúkọ Pastor Biodun Fatoyinbo gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ tẹ́lẹ̀.

UNILORIN ò tíì rí orúkọ Pastor Biodun Fatoyinbo gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ tẹ́lẹ̀.

Yunifasiti ti Ilorin ti fesi si ibeere fun ibeere akoole eko Padito Biodun Fatoyinbo, won si ni awon o tii ri akosile eko re.

Asoju oro akekoo, Ogbeni Kunle Akogun, ti so fun Punch pe, awon ti wo akodile awon akekoo ni iwe akosile, awon o si ri oruko pasito naa ti Busola Dakolo ati awon obinrin miiran fi esun kan pe o fi ipa ba awon lopo.

O ni: “mi o ti gbo esi lati ofisi akosile eko. A ti n wo o, amo a ko ti ri nkankan nipa re, ti a ba mo odun ti o setan tabi eko ti o ka, yoo fun wa ni irorun lati wa akosile re.”

Ki won to bere fun akosile re, won ni oludasile COZA bere eko re ni UNILORIN, amo ko setan nitori awon isele kan.

Won ni o lo si Osun State Polytechnic, Iree, nibi ti o ti gba iwe eri Higher National Diploma certificate. Iroyin kan naa tun ni o lo si Yunifasiti ti Benin leyin ti o kuro ni Yunifasiti ti Ilorin lai pari eko re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…