Nkechi Blessing Sunday ti ra ọkọ̀ Benz fún ara rẹ̀.
Gbajumo osere onitiata, Nkechi Blessing Sunday ti re oko Benz fun ara re, leyin ni odun kan seyin ti o ra oko Toyota Venza.
Osere naa gbe aworan oko re tuntun si ori instagram, o si ki awon egbe re. O ni,
“leyin odun kan, olorun ni asiko ti to???oluwa o seun leekan si…..ati awon omo egbe lenu ise mo dupe pupo fun ife ti e fi han simi.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…