Home Entertainment Igbákejì aṣojú (vp) ilé ìwé kan ní Ondo ti bá akẹ́kọ̀ọ́ tí kò lẹ́kọ̀ọ́ wí lórí Facebook.

Igbákejì aṣojú (vp) ilé ìwé kan ní Ondo ti bá akẹ́kọ̀ọ́ tí kò lẹ́kọ̀ọ́ wí lórí Facebook.

Arakunrin kan, Adeniji Emmanuel Sunday, igbakeji asoju(vice principal) ile iwe kan ni ipinle Ondo, ti ba omo kan ti o je akekoo okan lara awon ile iwe ti o n se asoju wi leyin ti omo na o bowo fun lori Facebook.

Igbakeji asoju naa ti o ni Marley Kesh ni omo naa n je, o pe omo naa ni “omo ti ko dara fun nnkankan”, o si ti ni oun maa di awon omode pa lori Facebook re. O ni,

Kii soro lati mo omo to wa lati ile bururku. Iru omo bee o ni ibowo fun awon obi re ati awon oluko re, ti o ba ri aye gan omo na won. Amo iparun nii gbeyin iru omo bee. Gege bi oluko, mo ma n ni ibasepo to peye pelu awon akekoo mi, awon akekoo mi naa si mo. Amo won ni ninu awon mejila, judas kan ma wa nibe. Omo ti e n wo yii je omo ti ko dara fun ohunkohun, ni irole yii mo ri ifiranse kan lori Facebook to ni ‘okunrin yii hw far’ mo koko ro pe boya asise ni, o si dami lohun pada pe ‘beenino ki lo n sele, a o si ni ile iwe oo’. Mo ti pinnu lati di gbogbo awon omode ori Facebook mi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…